Jóòbù 17:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ó ti sọ mí di ẹni ẹ̀gàn* láàárín àwọn èèyàn,+Tí mo fi di ẹni tí wọ́n ń tutọ́ sí lójú.+