Jóòbù 30:9, 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àmọ́ wọ́n ń fi mí ṣe yẹ̀yẹ́ báyìí kódà nínú orin wọn;+Mo ti di ẹni ẹ̀gàn* lójú wọn.+ 10 Wọ́n kórìíra mi, wọ́n sì jìnnà sí mi;+Ó yá wọn lára láti tutọ́ sí mi lójú.+
9 Àmọ́ wọ́n ń fi mí ṣe yẹ̀yẹ́ báyìí kódà nínú orin wọn;+Mo ti di ẹni ẹ̀gàn* lójú wọn.+ 10 Wọ́n kórìíra mi, wọ́n sì jìnnà sí mi;+Ó yá wọn lára láti tutọ́ sí mi lójú.+