Òwe 6:25, 26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Má ṣe jẹ́ kí ẹwà rẹ̀ wù ọ́+Tàbí kí o jẹ́ kó fi ojú rẹ̀ tó ń fani mọ́ra mú ọ,26 Ní tìtorí aṣẹ́wó, èèyàn á di ẹni tí kò ní ju búrẹ́dì kan ṣoṣo lọ,+Ní ti obìnrin alágbèrè, ẹ̀mí* tó ṣeyebíye ló fi ń ṣe ìjẹ. Mátíù 5:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Àmọ́ mò ń sọ fún yín pé ẹnikẹ́ni tó bá tẹjú mọ́ obìnrin+ kan lọ́nà tí á fi wù ú láti bá a ṣe ìṣekúṣe, ó ti bá a ṣe àgbèrè nínú ọkàn rẹ̀.+
25 Má ṣe jẹ́ kí ẹwà rẹ̀ wù ọ́+Tàbí kí o jẹ́ kó fi ojú rẹ̀ tó ń fani mọ́ra mú ọ,26 Ní tìtorí aṣẹ́wó, èèyàn á di ẹni tí kò ní ju búrẹ́dì kan ṣoṣo lọ,+Ní ti obìnrin alágbèrè, ẹ̀mí* tó ṣeyebíye ló fi ń ṣe ìjẹ.
28 Àmọ́ mò ń sọ fún yín pé ẹnikẹ́ni tó bá tẹjú mọ́ obìnrin+ kan lọ́nà tí á fi wù ú láti bá a ṣe ìṣekúṣe, ó ti bá a ṣe àgbèrè nínú ọkàn rẹ̀.+