Sáàmù 26:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Mo kórìíra àwùjọ àwọn aṣebi,+Mi ò sì jẹ́ bá àwọn ẹni burúkú kẹ́gbẹ́.*+ Òwe 6:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ohun mẹ́fà wà tí Jèhófà kórìíra;Bẹ́ẹ̀ ni, ohun méje tó jẹ́ ohun ìríra fún un:* Òwe 6:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ọkàn tó ń gbèrò ìkà+ àti ẹsẹ̀ tó ń sáré tete láti ṣe ibi,