Òwe 11:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àwọn tí ọkàn wọn burú jẹ́ ohun ìríra lójú Jèhófà,+Àmọ́ àwọn tí ọ̀nà wọn tọ́ ń mú inú rẹ̀ dùn.+ Sekaráyà 8:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ẹ má gbèrò ibi sí ara yín nínú ọkàn yín,+ ẹ má sì fẹ́ràn ìbúra èké,+ torí mo kórìíra gbogbo àwọn nǹkan yìí,’+ ni Jèhófà wí.” Málákì 2:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Torí mo kórìíra* ìkọ̀sílẹ̀,”+ ni Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí, “mo sì kórìíra ẹni tí ìwà ipá ti wọ̀ lẹ́wù,”* ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí. “Ẹ ṣọ́ ẹ̀mí tó ń darí yín, ẹ má sì hùwà àìṣòótọ́.+
17 Ẹ má gbèrò ibi sí ara yín nínú ọkàn yín,+ ẹ má sì fẹ́ràn ìbúra èké,+ torí mo kórìíra gbogbo àwọn nǹkan yìí,’+ ni Jèhófà wí.”
16 Torí mo kórìíra* ìkọ̀sílẹ̀,”+ ni Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí, “mo sì kórìíra ẹni tí ìwà ipá ti wọ̀ lẹ́wù,”* ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí. “Ẹ ṣọ́ ẹ̀mí tó ń darí yín, ẹ má sì hùwà àìṣòótọ́.+