Òwe 14:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ẹni tó bá ń fojú àbùkù wo ọmọnìkejì rẹ̀ ń dẹ́ṣẹ̀,Àmọ́ ẹni tó bá ń ṣàánú aláìní jẹ́ aláyọ̀.+