Òwe 31:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Àwọn èèyàn mọ ọkọ rẹ̀ dáadáa ní àwọn ẹnubodè ìlú,+Níbi tó máa ń jókòó sí láàárín àwọn àgbààgbà ilẹ̀ náà.
23 Àwọn èèyàn mọ ọkọ rẹ̀ dáadáa ní àwọn ẹnubodè ìlú,+Níbi tó máa ń jókòó sí láàárín àwọn àgbààgbà ilẹ̀ náà.