Rúùtù 4:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Bóásì wá lọ sí ẹnubodè ìlú,+ ó sì jókòó síbẹ̀. Sì wò ó, olùtúnrà tí Bóásì sọ̀rọ̀ rẹ̀+ ń kọjá lọ. Ni Bóásì bá sọ pé: “Èèyàn mi,* wá jókòó.” Torí náà, ó yà, ó sì jókòó. Jóòbù 29:7, 8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nígbà tí mo ṣì máa ń jáde lọ sí ẹnubodè ìlú,+Tí mo sì máa ń jókòó sí ojúde ìlú,+ 8 Àwọn ọ̀dọ́kùnrin máa rí mi, wọ́n á sì yà sẹ́gbẹ̀ẹ́,*Àwọn àgbà ọkùnrin pàápàá máa dìde, wọ́n á sì wà ní ìdúró.+
4 Bóásì wá lọ sí ẹnubodè ìlú,+ ó sì jókòó síbẹ̀. Sì wò ó, olùtúnrà tí Bóásì sọ̀rọ̀ rẹ̀+ ń kọjá lọ. Ni Bóásì bá sọ pé: “Èèyàn mi,* wá jókòó.” Torí náà, ó yà, ó sì jókòó.
7 Nígbà tí mo ṣì máa ń jáde lọ sí ẹnubodè ìlú,+Tí mo sì máa ń jókòó sí ojúde ìlú,+ 8 Àwọn ọ̀dọ́kùnrin máa rí mi, wọ́n á sì yà sẹ́gbẹ̀ẹ́,*Àwọn àgbà ọkùnrin pàápàá máa dìde, wọ́n á sì wà ní ìdúró.+