Òwe 17:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ẹni tó bá ń fi aláìní ṣẹ̀sín ń gan Ẹni tó dá a,+Ẹni tó bá sì ń yọ̀ nítorí àjálù tó bá ẹlòmíì kò ní lọ láìjìyà.+ Òwe 24:17, 18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Tí ọ̀tá rẹ bá ṣubú, má ṣe dunnú,Tó bá sì kọsẹ̀, má ṣe jẹ́ kí ọkàn rẹ yọ̀;+18 Nítorí Jèhófà yóò rí i, á sì bí i nínú,Á sì yí ìbínú rẹ̀ kúrò lórí rẹ̀.*+
5 Ẹni tó bá ń fi aláìní ṣẹ̀sín ń gan Ẹni tó dá a,+Ẹni tó bá sì ń yọ̀ nítorí àjálù tó bá ẹlòmíì kò ní lọ láìjìyà.+
17 Tí ọ̀tá rẹ bá ṣubú, má ṣe dunnú,Tó bá sì kọsẹ̀, má ṣe jẹ́ kí ọkàn rẹ yọ̀;+18 Nítorí Jèhófà yóò rí i, á sì bí i nínú,Á sì yí ìbínú rẹ̀ kúrò lórí rẹ̀.*+