ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóòbù 31:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Ṣé inú mi ti dùn rí torí pé ọ̀tá mi pa run,+

      Tàbí kí n fi ṣe yẹ̀yẹ́ torí ohun burúkú ṣẹlẹ̀ sí i?

  • Òwe 17:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Ẹni tó bá ń fi aláìní ṣẹ̀sín ń gan Ẹni tó dá a,+

      Ẹni tó bá sì ń yọ̀ nítorí àjálù tó bá ẹlòmíì kò ní lọ láìjìyà.+

  • Òwe 25:21, 22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Tí ebi bá ń pa ọ̀tá rẹ,* fún un ní oúnjẹ jẹ;

      Tí òùngbẹ bá sì ń gbẹ ẹ́, fún un ní omi mu,+

      22 Torí ṣe ni wàá máa kó ẹyin iná jọ lé e lórí,*+

      Jèhófà yóò sì san èrè fún ọ.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́