ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 3:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Lẹ́yìn náà, wọ́n gbọ́ ohùn Jèhófà Ọlọ́run nígbà tó ń rìn nínú ọgbà ní àkókò tí atẹ́gùn máa ń fẹ́ lọ́wọ́ ìrọ̀lẹ́,* ọkùnrin náà àti ìyàwó rẹ̀ sì lọ fara pa mọ́ sáàárín àwọn igi inú ọgbà, kí Jèhófà Ọlọ́run má bàa rí wọn.

  • Òwe 28:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Ẹni tó bá ń bo àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ mọ́lẹ̀ kò ní ṣàṣeyọrí,+

      Àmọ́ ẹni tó bá jẹ́wọ́, tó sì fi wọ́n sílẹ̀ la ó fi àánú hàn sí.+

  • Ìṣe 5:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Pétérù sọ fún un pé: “Sọ fún mi, ṣé iye tí ẹ̀yin méjèèjì ta ilẹ̀ náà nìyí?” Ó sọ pé: “Bẹ́ẹ̀ ni, iye rẹ̀ nìyẹn.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́