Òwe 15:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ọkàn olódodo máa ń ṣe àṣàrò kí ó tó dáhùn,*+Àmọ́ ẹnu ẹni burúkú máa ń tú ọ̀rọ̀ burúkú jáde.