ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóòbù 12:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Ọgbọ́n àti agbára ńlá wà lọ́dọ̀ rẹ̀;+

      Ó ní ìmọ̀ràn àti òye.+

  • Sáàmù 8:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Kí ni ẹni kíkú jẹ́ tí o fi ń fi í sọ́kàn

      Àti ọmọ aráyé tí o fi ń tọ́jú rẹ̀?+

  • Àìsáyà 40:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 “Ta lẹ lè fi mí wé bóyá mo bá a dọ́gba?” ni Ẹni Mímọ́ wí.

  • Àìsáyà 55:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 “Torí bí ọ̀run ṣe ga ju ayé lọ,

      Bẹ́ẹ̀ ni ọ̀nà mi ga ju ọ̀nà yín,

      Èrò mi sì ga ju èrò yín.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́