Jóòbù 36:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Lóòótọ́, Ọlọ́run lágbára,+ kì í sì í kọ ẹnì kankan sílẹ̀;Agbára òye* rẹ̀ pọ̀ gan-an. Sáàmù 147:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Olúwa wa tóbi, agbára rẹ̀ sì pọ̀;+Òye rẹ̀ ò ṣeé díwọ̀n.+ Àìsáyà 40:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ta ló ti bá fikùn lukùn kó lè ní òye,Tàbí ta ló kọ́ ọ ní ọ̀nà ìdájọ́ òdodo,Tó kọ́ ọ ní ìmọ̀,Tàbí tó fi ọ̀nà òye tòótọ́ hàn án?+ Jeremáyà 10:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Òun ni Aṣẹ̀dá ayé tó fi agbára rẹ̀ dá a,Ẹni tó fi ọgbọ́n rẹ̀ dá ilẹ̀ tó ń mú èso jáde+Tó sì fi òye rẹ̀ na ọ̀run bí aṣọ.+ Róòmù 11:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Nítorí “ta ló mọ èrò Jèhófà,* ta sì ni agbani-nímọ̀ràn rẹ̀?”+
14 Ta ló ti bá fikùn lukùn kó lè ní òye,Tàbí ta ló kọ́ ọ ní ọ̀nà ìdájọ́ òdodo,Tó kọ́ ọ ní ìmọ̀,Tàbí tó fi ọ̀nà òye tòótọ́ hàn án?+
12 Òun ni Aṣẹ̀dá ayé tó fi agbára rẹ̀ dá a,Ẹni tó fi ọgbọ́n rẹ̀ dá ilẹ̀ tó ń mú èso jáde+Tó sì fi òye rẹ̀ na ọ̀run bí aṣọ.+