-
Dáníẹ́lì 4:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Mo lá àlá kan tó dẹ́rù bà mí. Bí mo ṣe dùbúlẹ̀ sórí ibùsùn mi, àwọn àwòrán àti ìran tí mo rí dáyà já mi.+