-
Dáníẹ́lì 4:24, 25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Ìtumọ̀ rẹ̀ nìyí, ọba; àṣẹ tí Ẹni Gíga Jù Lọ pa, tó gbọ́dọ̀ ṣẹlẹ̀ sí olúwa mi ọba ni. 25 Wọ́n máa lé ọ kúrò láàárín àwọn èèyàn, ọ̀dọ̀ àwọn ẹranko ni wàá máa gbé, a sì máa fún ọ ní ewéko jẹ bí akọ màlúù; ìrì ọ̀run máa sẹ̀ sí ọ lára,+ ìgbà méje + sì máa kọjá lórí rẹ,+ títí o fi máa mọ̀ pé Ẹni Gíga Jù Lọ ni Alákòóso nínú ìjọba aráyé, ẹni tó bá sì wù ú ló ń gbé e fún.+
-