Sáàmù 19:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Kí ọ̀rọ̀ ẹnu mi àti àṣàrò ọkàn miMáa múnú rẹ dùn,+ Jèhófà, Àpáta mi+ àti Olùràpadà mi.+ Àìsáyà 38:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Wò ó! Dípò àlàáfíà, ìbànújẹ́ ńlá ló bá mi;Àmọ́ torí ìfẹ́ tí o ní sí mi,*O pa mí mọ́ kúrò nínú kòtò ìparun.+ O ti ju gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ mi sí ẹ̀yìn rẹ.*+
17 Wò ó! Dípò àlàáfíà, ìbànújẹ́ ńlá ló bá mi;Àmọ́ torí ìfẹ́ tí o ní sí mi,*O pa mí mọ́ kúrò nínú kòtò ìparun.+ O ti ju gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ mi sí ẹ̀yìn rẹ.*+