- 
	                        
            
            Sáàmù 139:11, 12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        11 Tí mo bá sọ pé: “Dájúdájú, òkùnkùn yóò fi mí pa mọ́!” Nígbà náà, òkùnkùn tó yí mi ká yóò di ìmọ́lẹ̀. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Émọ́sì 9:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        3 Bí wọ́n bá fara pa mọ́ sórí òkè Kámẹ́lì, Ibẹ̀ ni màá ti wá wọn kàn, màá sì mú wọn.+ Bí wọ́n bá sì fara pa mọ́ kúrò ní ojú mi ní ìsàlẹ̀ òkun, Ibẹ̀ ni màá ti pàṣẹ fún ejò, á sì bù wọ́n ṣán. 
 
-