Àìsáyà 30:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 “Àwọn alágídí ọmọ gbé,”+ ni Jèhófà wí,“Àwọn tó ń ṣe ohun tí mi ò ní lọ́kàn,+Tí wọ́n gbìmọ̀ pọ̀,* àmọ́ tí kì í ṣe nípasẹ̀ ẹ̀mí mi,Kí wọ́n lè dá ẹ̀ṣẹ̀ kún ẹ̀ṣẹ̀.
30 “Àwọn alágídí ọmọ gbé,”+ ni Jèhófà wí,“Àwọn tó ń ṣe ohun tí mi ò ní lọ́kàn,+Tí wọ́n gbìmọ̀ pọ̀,* àmọ́ tí kì í ṣe nípasẹ̀ ẹ̀mí mi,Kí wọ́n lè dá ẹ̀ṣẹ̀ kún ẹ̀ṣẹ̀.