Jóòbù 10:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 O mọ̀ pé mi ò jẹ̀bi,+Kò sì sí ẹni tó lè gbà mí lọ́wọ́ rẹ.+ Jóòbù 16:16, 17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ojú mi ti pọ́n torí mò ń sunkún,+Òkùnkùn biribiri* sì wà ní ìpéǹpéjú mi,17 Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ọwọ́ mi ò hùwà ipá kankan,Àdúrà mi sì mọ́. Jóòbù 34:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Torí Jóòbù sọ pé, ‘Mo jàre,+Àmọ́ Ọlọ́run ti fi ìdájọ́ òdodo dù mí.+
16 Ojú mi ti pọ́n torí mò ń sunkún,+Òkùnkùn biribiri* sì wà ní ìpéǹpéjú mi,17 Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ọwọ́ mi ò hùwà ipá kankan,Àdúrà mi sì mọ́.