-
Jóòbù 34:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Torí o sọ pé, ‘Èèyàn kì í jèrè
Tó bá ń gbìyànjú láti ṣe ohun tí Ọlọ́run fẹ́.’+
-
-
Sáàmù 73:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ó dájú pé lásán ni mo pa ọkàn mi mọ́,
Tí mo sì wẹ ọwọ́ mi mọ́ pé mo jẹ́ aláìmọwọ́mẹsẹ̀.+
-