ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 10:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Àmọ́, o rí ìjàngbọ̀n àti ìdààmú.

      Ò ń wò ó, o sì gbé ìgbésẹ̀.+

      Ọ̀dọ̀ rẹ ni àwọn tó rin àrìnfẹsẹ̀sí yíjú sí;+

      Ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ ọmọ aláìníbaba.*+

  • Sáàmù 140:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Mo mọ̀ pé Jèhófà máa gbèjà àwọn aláìní

      Á sì ṣèdájọ́ òdodo fún àwọn tálákà.+

  • Òwe 22:22, 23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Má ja tálákà lólè torí pé kò ní lọ́wọ́,+

      Má sì fojú aláìní gbolẹ̀ ní ẹnubodè,+

      23 Nítorí Jèhófà fúnra rẹ̀ yóò gba ẹjọ́ wọn rò+

      Yóò sì gba ẹ̀mí* àwọn tó lù wọ́n ní jìbìtì.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́