Sáàmù 10:17, 18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àmọ́ Jèhófà, wàá gbọ́ ẹ̀bẹ̀ àwọn oníwà pẹ̀lẹ́.+ Wàá mú ọkàn wọn dúró ṣinṣin,+ wàá sì fiyè sí wọn.+ 18 Wàá dá ẹjọ́ òdodo fún ọmọ aláìníbaba àti ẹni tí a ni lára,+Kí ẹni kíkú lásánlàsàn* má bàa dẹ́rù bà wọ́n mọ́.+ Sáàmù 22:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Nítorí kò gbójú fo ìyà tó ń jẹ ẹni tí ara ń ni, kò sì ṣàìka ìpọ́njú rẹ̀ sí;+Kò gbé ojú rẹ̀ pa mọ́ fún un.+ Nígbà tó ké pè é fún ìrànlọ́wọ́, ó gbọ́.+
17 Àmọ́ Jèhófà, wàá gbọ́ ẹ̀bẹ̀ àwọn oníwà pẹ̀lẹ́.+ Wàá mú ọkàn wọn dúró ṣinṣin,+ wàá sì fiyè sí wọn.+ 18 Wàá dá ẹjọ́ òdodo fún ọmọ aláìníbaba àti ẹni tí a ni lára,+Kí ẹni kíkú lásánlàsàn* má bàa dẹ́rù bà wọ́n mọ́.+
24 Nítorí kò gbójú fo ìyà tó ń jẹ ẹni tí ara ń ni, kò sì ṣàìka ìpọ́njú rẹ̀ sí;+Kò gbé ojú rẹ̀ pa mọ́ fún un.+ Nígbà tó ké pè é fún ìrànlọ́wọ́, ó gbọ́.+