Àìsáyà 55:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Kí ló dé tí ẹ fi ń sanwó fún ohun tí kì í ṣe oúnjẹ,Kí ló sì dé tí ẹ fi ń lo ohun tí ẹ ṣiṣẹ́ fún* sórí ohun tí kì í tẹ́ni lọ́rùn? Ẹ tẹ́tí sí mi dáadáa, kí ẹ sì jẹ ohun tó dáa,+Ohun tó dọ́ṣọ̀* sì máa mú inú yín dùn* gidigidi.+
2 Kí ló dé tí ẹ fi ń sanwó fún ohun tí kì í ṣe oúnjẹ,Kí ló sì dé tí ẹ fi ń lo ohun tí ẹ ṣiṣẹ́ fún* sórí ohun tí kì í tẹ́ni lọ́rùn? Ẹ tẹ́tí sí mi dáadáa, kí ẹ sì jẹ ohun tó dáa,+Ohun tó dọ́ṣọ̀* sì máa mú inú yín dùn* gidigidi.+