Àìsáyà 25:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Lórí òkè yìí,+ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun máa se àkànṣe àsè tó dọ́ṣọ̀+Fún gbogbo èèyàn,Àkànṣe àsè tó ní wáìnì tó dáa,*Àsè tó dọ́ṣọ̀ tí mùdùnmúdùn kún inú rẹ̀,Àsè tó ní wáìnì tó dáa tí wọ́n sẹ́.
6 Lórí òkè yìí,+ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun máa se àkànṣe àsè tó dọ́ṣọ̀+Fún gbogbo èèyàn,Àkànṣe àsè tó ní wáìnì tó dáa,*Àsè tó dọ́ṣọ̀ tí mùdùnmúdùn kún inú rẹ̀,Àsè tó ní wáìnì tó dáa tí wọ́n sẹ́.