-
Hósíà 11:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Mi ò ní tú ìbínú mi tó ń jó fòfò jáde.
Mi ò ní pa Éfúrémù run mọ́,+
Nítorí Ọlọ́run ni mí, èmi kì í ṣe èèyàn,
Ẹni Mímọ́ tó wà láàárín rẹ;
Mi ò sì ní fi ìbínú wá sọ́dọ̀ rẹ.
-