Sáàmù 9:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ṣojú rere sí mi, Jèhófà; wo ìyà tí àwọn tó kórìíra mi fi ń jẹ mí,Ìwọ tó gbé mi dìde láti àwọn ẹnubodè ikú,+ Mátíù 16:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Bákan náà, mò ń sọ fún ọ pé: Ìwọ ni Pétérù,+ orí àpáta yìí+ sì ni màá kọ́ ìjọ mi sí, àwọn ibodè Isà Òkú* kò sì ní borí rẹ̀.
13 Ṣojú rere sí mi, Jèhófà; wo ìyà tí àwọn tó kórìíra mi fi ń jẹ mí,Ìwọ tó gbé mi dìde láti àwọn ẹnubodè ikú,+ Mátíù 16:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Bákan náà, mò ń sọ fún ọ pé: Ìwọ ni Pétérù,+ orí àpáta yìí+ sì ni màá kọ́ ìjọ mi sí, àwọn ibodè Isà Òkú* kò sì ní borí rẹ̀.
18 Bákan náà, mò ń sọ fún ọ pé: Ìwọ ni Pétérù,+ orí àpáta yìí+ sì ni màá kọ́ ìjọ mi sí, àwọn ibodè Isà Òkú* kò sì ní borí rẹ̀.