ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 30:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Jèhófà, o ti gbé mi* sókè látinú Isà Òkú.*+

      O mú kí n wà láàyè, o ò sì jẹ́ kí n rì sínú kòtò.*+

  • Àìsáyà 38:9, 10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Ìwé* tí Hẹsikáyà ọba Júdà kọ nígbà tó ń ṣàìsàn, tí ara rẹ̀ sì yá.

      10 Mo sọ pé: “Ní àárín ọjọ́ ayé mi,

      Mo gbọ́dọ̀ wọnú àwọn ẹnubodè Isà Òkú.*

      A máa fi àwọn ọdún mi tó kù dù mí.”

  • Ìfihàn 1:17, 18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Nígbà tí mo rí i, mo ṣubú síbi ẹsẹ̀ rẹ̀ bíi pé mo ti kú.

      Ó gbé ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ lé mi, ó sì sọ pé: “Má bẹ̀rù. Èmi ni Ẹni Àkọ́kọ́+ àti Ẹni Ìkẹyìn+ 18 àti alààyè,+ mo ti kú tẹ́lẹ̀,+ àmọ́ wò ó! mo wà láàyè títí láé àti láéláé,+ mo sì ní kọ́kọ́rọ́ ikú àti ti Isà Òkú.*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́