Jóòbù 33:12, 13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àmọ́ ohun tí o sọ yìí ò tọ́, torí náà, màá dá ọ lóhùn: Ọlọ́run tóbi ju ẹni kíkú+ lọ fíìfíì. 13 Kí nìdí tí o fi ń ṣàròyé nípa Rẹ̀?+ Ṣé torí pé kò fèsì gbogbo ọ̀rọ̀ tí o sọ ni?+ Àìsáyà 45:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó mà ṣe fún ẹni tó ń bá Aṣẹ̀dá rẹ̀* fa nǹkan* o,Torí ó dà bí àfọ́kù ìkòkò lásánLáàárín àwọn àfọ́kù ìkòkò míì tó wà nílẹ̀! Ṣé ó yẹ kí amọ̀ sọ fún Amọ̀kòkò* pé: “Kí lò ń mọ?”+ Àbí ó yẹ kí iṣẹ́ rẹ sọ pé: “Kò ní ọwọ́”?*
12 Àmọ́ ohun tí o sọ yìí ò tọ́, torí náà, màá dá ọ lóhùn: Ọlọ́run tóbi ju ẹni kíkú+ lọ fíìfíì. 13 Kí nìdí tí o fi ń ṣàròyé nípa Rẹ̀?+ Ṣé torí pé kò fèsì gbogbo ọ̀rọ̀ tí o sọ ni?+
9 Ó mà ṣe fún ẹni tó ń bá Aṣẹ̀dá rẹ̀* fa nǹkan* o,Torí ó dà bí àfọ́kù ìkòkò lásánLáàárín àwọn àfọ́kù ìkòkò míì tó wà nílẹ̀! Ṣé ó yẹ kí amọ̀ sọ fún Amọ̀kòkò* pé: “Kí lò ń mọ?”+ Àbí ó yẹ kí iṣẹ́ rẹ sọ pé: “Kò ní ọwọ́”?*