Jóòbù 40:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “Wò ó! Mi ò já mọ́ nǹkan kan.+ Kí ni màá fi dá ọ lóhùn? Mo fi ọwọ́ bo ẹnu mi.+