Sáàmù 39:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Mi ò lè sọ̀rọ̀;Mi ò lè la ẹnu mi,+Nítorí iṣẹ́ ọwọ́ rẹ ni.+ Òwe 30:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Tí o bá ti jẹ́ kí ìwà òmùgọ̀ mú kí o gbéra ga+Tàbí tí o bá ti gbèrò láti ṣe bẹ́ẹ̀,Fi ọwọ́ bo ẹnu rẹ.+
32 Tí o bá ti jẹ́ kí ìwà òmùgọ̀ mú kí o gbéra ga+Tàbí tí o bá ti gbèrò láti ṣe bẹ́ẹ̀,Fi ọwọ́ bo ẹnu rẹ.+