- 
	                        
            
            2 Kíróníkà 25:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        9 Ni Amasááyà bá sọ fún èèyàn Ọlọ́run tòótọ́ náà pé: “Ọgọ́rùn-ún (100) tálẹ́ńtì tí mo wá fún àwọn ọmọ ogun Ísírẹ́lì ńkọ́?” Èèyàn Ọlọ́run tòótọ́ náà fèsì pé: “Jèhófà mọ bó ṣe máa fi èyí tó pọ̀ ju bẹ́ẹ̀ san án fún ọ.”+ 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Òwe 22:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        4 Èrè ìrẹ̀lẹ̀ àti ìbẹ̀rù Jèhófà Ni ọrọ̀ àti ògo àti ìyè.+ 
 
-