1 Sámúẹ́lì 1:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Inú Hánà bà jẹ́* gan-an, ó bẹ̀rẹ̀ sí í gbàdúrà sí Jèhófà,+ ó sì ń sunkún tẹ̀dùntẹ̀dùn. Jóòbù 10:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “Mo* kórìíra ayé mi gidigidi.+ Mi ò ní pa bó ṣe ń ṣe mi mọ́ra. Màá sọ̀rọ̀ látinú ẹ̀dùn ọkàn* tó bá mi! Òwe 14:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ọkàn èèyàn mọ ìbànújẹ́ rẹ̀,*Àjèjì kò sì lè pín nínú ayọ̀ rẹ̀.
10 “Mo* kórìíra ayé mi gidigidi.+ Mi ò ní pa bó ṣe ń ṣe mi mọ́ra. Màá sọ̀rọ̀ látinú ẹ̀dùn ọkàn* tó bá mi!