Sáàmù 62:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Èémí lásán ni àwọn ọmọ èèyàn,Ẹ̀tàn ni àwọn ọmọ aráyé.+ Tí a bá gbé gbogbo wọn lórí òṣùwọ̀n, wọ́n fúyẹ́ ju èémí lásán.+ Sáàmù 144:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Èèyàn dà bí èémí lásán;+Àwọn ọjọ́ rẹ̀ dà bí òjìji tó ń kọjá lọ.+ Oníwàásù 6:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ta ló mọ ohun tó dára jù lọ fún èèyàn láti fi ayé rẹ̀ ṣe láàárín ọjọ́ díẹ̀ tó máa fi gbé ìgbé ayé asán, èyí tó máa kọjá lọ bí òjìji?+ Àbí ta ló lè sọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ lábẹ́ ọ̀run* fún èèyàn lẹ́yìn tó bá ti lọ?
9 Èémí lásán ni àwọn ọmọ èèyàn,Ẹ̀tàn ni àwọn ọmọ aráyé.+ Tí a bá gbé gbogbo wọn lórí òṣùwọ̀n, wọ́n fúyẹ́ ju èémí lásán.+
12 Ta ló mọ ohun tó dára jù lọ fún èèyàn láti fi ayé rẹ̀ ṣe láàárín ọjọ́ díẹ̀ tó máa fi gbé ìgbé ayé asán, èyí tó máa kọjá lọ bí òjìji?+ Àbí ta ló lè sọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ lábẹ́ ọ̀run* fún èèyàn lẹ́yìn tó bá ti lọ?