- 
	                        
            
            Sáàmù 94:3, 4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        3 Ìgbà wo, Jèhófà, Ìgbà wo ni àwọn ẹni burúkú ò ní yọ̀ mọ́?+ 4 Wọ́n ń sọ̀rọ̀ yàùyàù, wọ́n sì ń sọ̀rọ̀ ìgbéraga; Gbogbo àwọn aṣebi ń fọ́nnu nípa ara wọn. 
 
-