ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 22:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Ìgbà náà ni Dóẹ́gì+ ọmọ Édómù tó ń bójú tó àwọn ìránṣẹ́ Sọ́ọ̀lù fèsì pé:+ “Mo rí ọmọ Jésè tó wá sí Nóbù lọ́dọ̀ Áhímélékì ọmọ Áhítúbù.+

  • 1 Sámúẹ́lì 22:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Ìgbà náà ni ọba sọ fún Dóẹ́gì+ pé: “Ìwọ, lọ pa àwọn àlùfáà náà!” Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, Dóẹ́gì ọmọ Édómù+ lọ pa àwọn àlùfáà náà fúnra rẹ̀. Ọkùnrin márùnlélọ́gọ́rin (85) tó ń wọ éfódì+ tí a fi aṣọ ọ̀gbọ̀* ṣe ni ó pa lọ́jọ́ yẹn.

  • Sáàmù 109:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Nítorí àwọn ẹni burúkú àti àwọn ẹlẹ́tàn ń la ẹnu wọn sí mi.

      Wọ́n ń fi ahọ́n èké sọ̀rọ̀ nípa mi;+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́