- 
	                        
            
            Sáàmù 10:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        4 Ìgbéraga kì í jẹ́ kí ẹni burúkú ṣe ìwádìí kankan; Gbogbo èrò rẹ̀ ni pé: “Kò sí Ọlọ́run.”+ 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Róòmù 1:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        21 Nítorí bó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n mọ Ọlọ́run, wọn ò yìn ín lógo bí Ọlọ́run, bẹ́ẹ̀ ni wọn ò dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀, ìrònú wọn ò mọ́gbọ́n dání, ọkàn wọn tó ti kú tipiri sì ṣókùnkùn.+ 
 
-