ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 14:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Òmùgọ̀* sọ lọ́kàn rẹ̀ pé:

      “Kò sí Jèhófà.”+

      Ìwà ìbàjẹ́ ni wọ́n ń hù, ìṣesí wọn sì jẹ́ ohun ìríra;

      Kò sí ẹni tó ń ṣe rere.+

       2 Àmọ́ Jèhófà ń bojú wo àwọn ọmọ èèyàn láti ọ̀run

      Láti rí i bóyá ẹnì kan wà tó ní ìjìnlẹ̀ òye, bóyá ẹnì kan wà tó ń wá Jèhófà.+

  • Sáàmù 53:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 53 Òmùgọ̀* sọ lọ́kàn rẹ̀ pé:

      “Kò sí Jèhófà.”+

      Ìwà àìtọ́ wọn burú, ó sì jẹ́ ohun ìríra;

      Kò sí ẹni tó ń ṣe rere.+

  • Sefanáyà 1:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Ní àkókò yẹn, màá fi fìtílà wá inú Jerúsálẹ́mù fínnífínní,

      Màá sì pe àwọn tó dẹra nù* wá jíhìn, àwọn tó ń sọ nínú ọkàn wọn pé,

      ‘Jèhófà kò ní ṣe rere, kò sì ní ṣe búburú.’+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́