-
1 Sámúẹ́lì 24:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Àwọn ọkùnrin Dáfídì sọ fún un pé: “Ọjọ́ yìí ni Jèhófà sọ fún ọ nípa rẹ̀ pé, ‘Wò ó! Màá fi ọ̀tá rẹ lé ọ lọ́wọ́,+ o lè ṣe ohunkóhun tó bá dára ní ojú rẹ sí i.’” Torí náà, Dáfídì dìde, ó sì rọra gé etí aṣọ àwọ̀lékè tí kò lápá tí Sọ́ọ̀lù wọ̀.
-
-
Òwe 26:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Ẹni tó gbẹ́ kòtò yóò já sínú rẹ̀,
Ẹni tó bá sì yí òkúta kúrò, òkúta náà yóò pa dà sórí rẹ̀.+
-