ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 52:5, 6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Ìdí nìyẹn tí Ọlọ́run yóò fi mú ọ balẹ̀ láìtún gbérí mọ́;+

      Yóò gbá ọ mú, yóò sì fà ọ́ kúrò nínú àgọ́ rẹ;+

      Yóò fà ọ́ tu kúrò ní ilẹ̀ alààyè.+ (Sélà)

       6 Àwọn olódodo á rí i, ẹnu á yà wọ́n,+

      Wọ́n á sì fi í rẹ́rìn-ín.+

  • Sáàmù 64:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Olódodo á máa yọ̀ nínú Jèhófà, á sì fi í ṣe ibi ààbò rẹ̀;+

      Gbogbo àwọn tí ọkàn wọn dúró ṣinṣin á máa ṣògo.*

  • Ìsíkíẹ́lì 25:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Màá gbẹ̀san lára wọn lọ́nà tó lé kenkà, màá fi ìbínú jẹ wọ́n níyà, wọ́n á sì wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà nígbà tí mo bá gbẹ̀san lára wọn.”’”

  • Ìfihàn 18:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 “Máa yọ̀ nítorí rẹ̀, ìwọ ọ̀run+ àti ẹ̀yin ẹni mímọ́,+ ẹ̀yin àpọ́sítélì àti wòlíì, torí pé Ọlọ́run ti kéde ìdájọ́ sórí rẹ̀ nítorí yín!”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́