-
Sáàmù 68:2, 3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Bí afẹ́fẹ́ ṣe ń gbá èéfín lọ, bẹ́ẹ̀ ni kí o gbá wọn lọ;
Bí ìda ṣe ń yọ́ níwájú iná,
Bẹ́ẹ̀ ni kí àwọn ẹni burúkú ṣègbé níwájú Ọlọ́run.+
-