- 
	                        
            
            Sáàmù 107:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        19 Wọ́n á ké pe Jèhófà fún ìrànlọ́wọ́ nítorí wàhálà tó bá wọn; Á sì gbà wọ́n nínú ìnira wọn. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Sáàmù 107:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        22 Kí wọ́n rú ẹbọ ọpẹ́,+ Kí wọ́n sì máa fi igbe ayọ̀ kéde àwọn iṣẹ́ rẹ̀. 
 
-