1 Kíróníkà 11:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àwọn tó ń gbé ní Jébúsì pẹ̀gàn Dáfídì pé: “O ò ní wọ ibí yìí!”+ Síbẹ̀, Dáfídì gba ibi ààbò Síónì,+ èyí tó wá di Ìlú Dáfídì.+ Sáàmù 48:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Gíga rẹ̀ rẹwà, ayọ̀ gbogbo ayé,+Òkè Síónì tó jìnnà réré ní àríwá,Ìlú Ọba Títóbi Lọ́lá.+ 3 Nínú àwọn ilé gogoro rẹ̀ tó láàbò,Ọlọ́run ti jẹ́ kí a mọ̀ pé òun ni ibi ààbò.*+ Sáàmù 132:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Nítorí Jèhófà ti yan Síónì;+Ó fẹ́ kó jẹ́ ibùgbé rẹ̀, ó ní:+
5 Àwọn tó ń gbé ní Jébúsì pẹ̀gàn Dáfídì pé: “O ò ní wọ ibí yìí!”+ Síbẹ̀, Dáfídì gba ibi ààbò Síónì,+ èyí tó wá di Ìlú Dáfídì.+
2 Gíga rẹ̀ rẹwà, ayọ̀ gbogbo ayé,+Òkè Síónì tó jìnnà réré ní àríwá,Ìlú Ọba Títóbi Lọ́lá.+ 3 Nínú àwọn ilé gogoro rẹ̀ tó láàbò,Ọlọ́run ti jẹ́ kí a mọ̀ pé òun ni ibi ààbò.*+