- 
	                        
            
            Jóòbù 19:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        13 Ó ti lé àwọn arákùnrin mi jìnnà réré sí mi, Àwọn tó sì mọ̀ mí ti kúrò lọ́dọ̀ mi.+ 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Jòhánù 1:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        11 Ó wá sí ilé òun fúnra rẹ̀, àmọ́ àwọn èèyàn rẹ̀ ò gbà á. 
 
-