Sáàmù 31:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ṣojú rere sí mi, Jèhófà, torí mo wà nínú ìdààmú. Ìrora ti sọ ojú mi di bàìbàì,+ àárẹ̀ sì ti bá gbogbo ara mi.*+ Sáàmù 40:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jọ̀ọ́ Jèhófà, jẹ́ kó wù ọ́ láti gbà mí sílẹ̀.+ Jèhófà, tètè wá ràn mí lọ́wọ́.+
9 Ṣojú rere sí mi, Jèhófà, torí mo wà nínú ìdààmú. Ìrora ti sọ ojú mi di bàìbàì,+ àárẹ̀ sì ti bá gbogbo ara mi.*+