-
Sáàmù 38:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Tètè wá ràn mí lọ́wọ́,
Jèhófà, ìgbàlà mi.+
-
-
Sáàmù 70:1-5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Kí àwọn tí inú wọn ń dùn sí àjálù tó bá mi
Sá pa dà nínú ẹ̀tẹ́.
3 Kí àwọn tó ń sọ pé: “Àháà! Àháà!”
Fi ìtìjú sá pa dà.
Kí àwọn tó nífẹ̀ẹ́ àwọn iṣẹ́ ìgbàlà rẹ máa sọ nígbà gbogbo pé:
“Ẹ gbé Ọlọ́run ga!”
-