-
Sáàmù 40:13-17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Jọ̀ọ́ Jèhófà, jẹ́ kó wù ọ́ láti gbà mí sílẹ̀.+
Jèhófà, tètè wá ràn mí lọ́wọ́.+
14 Kí ìtìjú àti ẹ̀tẹ́ bá
Gbogbo àwọn tó fẹ́ gba ẹ̀mí mi.*
Kí àwọn tí inú wọn ń dùn sí àjálù tó bá mi
Sá pa dà nínú ẹ̀tẹ́.
15 Ní ti àwọn tó ń sọ nípa mi pé: “Àháà! Àháà!”
Kí jìnnìjìnnì bò wọ́n nítorí ìtìjú tó dé bá wọn.
Kí àwọn tó nífẹ̀ẹ́ àwọn iṣẹ́ ìgbàlà rẹ máa sọ nígbà gbogbo pé:
“Ẹ gbé Jèhófà ga.”+
17 Àmọ́ aláìní ni mí, mi ò sì ní olùrànlọ́wọ́;
Kí Jèhófà fiyè sí mi.
-