Sáàmù 17:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Dáàbò bò mí lọ́wọ́ àwọn ẹni burúkú tó ń gbéjà kò mí. Lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá alénimádẹ̀yìn* tí wọ́n yí mi ká.+ Sáàmù 17:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ní báyìí, wọ́n ti ká wa mọ́;+Wọ́n ń wá ọ̀nà tí wọ́n á fi gbé wa ṣubú.*
9 Dáàbò bò mí lọ́wọ́ àwọn ẹni burúkú tó ń gbéjà kò mí. Lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá alénimádẹ̀yìn* tí wọ́n yí mi ká.+