- 
	                        
            
            1 Àwọn Ọba 21:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        7 Jésíbẹ́lì ìyàwó rẹ̀ sọ fún un pé: “Ìwọ kọ́ lò ń ṣàkóso lórí Ísírẹ́lì ni? Dìde, jẹun, kí o sì jẹ́ kí inú rẹ dùn. Màá fún ọ ní ọgbà àjàrà Nábótì ará Jésírẹ́lì.”+ 
 
-