- 
	                        
            
            Sáàmù 89:50, 51Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        50 Jèhófà, rántí ẹ̀gàn tí wọ́n kó bá ìránṣẹ́ rẹ; Bí mo ṣe fara da ẹ̀gàn gbogbo èèyàn;* 51 Jèhófà, rántí bí àwọn ọ̀tá rẹ ṣé ń sọ̀kò ọ̀rọ̀; Bí wọ́n ṣe pẹ̀gàn gbogbo ìṣísẹ̀ ẹni àmì òróró rẹ. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Àìsáyà 52:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        5 “Kí wá ni kí n ṣe níbí?” ni Jèhófà wí. “Ọ̀fẹ́ ni wọ́n kó àwọn èèyàn mi lọ. 
 
-